Categories
JSS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON

Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun alalaye Gbolohun Ibeere Gbolohun ase Gbolohun ebe Gbolohun ayisodi   Gbolohun alalaye:Eyi ni a fi n se iroyin bi isele tabi nnkan se ri fun […]

Categories
JSS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE – SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA

Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo Oro ayalo Apetunpe abbl.   Atunyewo faweli ati konsonanti faweli ni iro ti a pe nigba ti ko si idiwo fun eemi.   Iro faweli […]

Acadlly

You cannot copy content of this page