Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU LORI ISORI ORO EDE YORUBA

Apeere gbolohun lori oro – oruko ni ipo alo: O mu emu Ajadi fo agbe Ekundayo ko ile alaja Oro oruko ni ipo eyan Okunrin oloro naa kun i afemojumo Aja ode pa etu nla Ewure Toorera ni won ji Ile olowo naa rewa ORISII ORO ORUKO Oruko eniyan –           Bisi, Dele Oruko eranko                        […]

AKORI EKO: ITESIWAJU LORI ISORI ORO EDE YORUBA Read More »