Yoruba

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA Apejuwe iro faweli A le sapejuwe iro faweli ni ona merin wonyi; Ipo ti afase wa Apa kan ara ahon to gbe soke ju lo ninu enu Bi apa to ga soke naa se ga to ninu enu Ipo ti ete wa Ipo ti afase wa: Afase […]

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA Read More ยป