Yoruba

AKOLE ISE: Akoto ode-oni

Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin metodiisi, katoliki ati CMS se ipade lori akoto ede […]

AKOLE ISE: Akoto ode-oni Read More ยป