Yoruba

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN)

Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro. Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji; Iro ohun geere Iro ohun eleyoo Iro ohun geere: Eyi ni iro ohun ti o duro ni ori silebu lai ni eyo rara. Awon iro bee ni; Iro ohun oke ( […]

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN) Read More ยป