Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa Igba lona ogun …

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA Read More »