Yoruba

AKORI EKO: IYATO TI O WA LARIN ORO APONLE ATI APOLA APONLE

Oro aponle je eyo oro kan ninu ihun gbolohun ti o maa n pon oro – ise. Ise re gan-an ni lati se afihan itumo fun apola ise ninu gbolohun. Bi apeere: (i) Tunde rin: (ii) Tunde rin jaujau Tunde rin kemokemo Tunde rin pelepele Gholohun (i) je oro ise alaigbagbo (rin) ko I oro …

AKORI EKO: IYATO TI O WA LARIN ORO APONLE ATI APOLA APONLE Read More »