Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu (a) Oro apejuwe le yan oro – oruko ni ipo oluwa. Apeere; – Oruko rere san ju wura oun fadaka lo – Iwa bukuku ko […]
![Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun 1 Yoruba](http://acadlly.b-cdn.net/wp-content/uploads/2022/07/Yoruba.jpg)
Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu (a) Oro apejuwe le yan oro – oruko ni ipo oluwa. Apeere; – Oruko rere san ju wura oun fadaka lo – Iwa bukuku ko […]
Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. Ise Oro-Oruko Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun – Oluwa ni oluse nnkan ninu gbolohun apeere; Ayinde ra aso Ojo je ewa Oro oruko maa n wa ni ipo abo ninu gbolohun – Eyi […]
Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re. Aroko oniroyin je aroko ti o jo mo iroyin sise. Eyi le je kiko sile tabi si so lenu. Awon Igbese/Ilara Kiko Aroko Oniroyin Mi mu ori-oro ti a fe ko nnkan le Ki ko koko ohun ti a fe […]
Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun onibo/olo po oro-ise Gbolohun Abode/Ele yo oro-ise Gbolohun Abode je gbolohun ti kii gun Gbolohun Abode kii ni ju oro-ise eyokan lo. Apeere, Bata re […]
Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION ) EKA ISE: ASA AKOLE ISE: ISINKU Isinku ni eye ikeyin ti a […]
Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu mi abbl. Aroko lori Ile-Iwe mi Oruko Ile-eko mi ni […]
Litireso apileko ere-onitan ni iwe ere atinude ti onkowe ko lati so ohun ti o sele ninu itan tabi ti o sele loju aye. Apeere iwe ere-onitan ni “Efusetan Aniwura ti Akinwumi Isola ko Onkawe ere-onitan gbode mo awon koko wonyi, O gbodo mo nipa igbesi-aye onkowe O gbodo mo itan inu iwe naa […]
Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A ni lati ronu jinle ki a si to ero okan wa ni okookan ninu ipinro […]
Asa isomoloruko je ona ti a n gba fun omo tuntun ni oruko ti yoo maa je titi lae ni ile Yoruba. Gbogbo ohun ti olodumare da saye lo ni oruko. oniruuru ohun-elo tabi eronja ni Yoruba si maa n lo ni gba Ikomojade . Ojo kefa ni Yoruba n so omo loruko, I ba […]
AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57 58 Eeji din logota 60-2=58 59 Ookan din logota 60-1=59 60 Ogota […]
Eyi ni litireso ti a se akosile ni gba ti imo mooko – mooka de si ile wa. Litireso apileko pin si ona meta, i Ewi ii Ere-Onitan iii Itan aroso Litireso Apileko – Itan aroso koko ti a gbodo tele ti a ba n ka litireso apileko itan aroso. Onkawe gbodo […]
Asa jeyo ninu Ede Yoruba ninu ipede bii owe, akanlo-ede, ewi ,ise sise abbl. Apeere OWE ASA TI O JEYO EKO TI AWON ASA YII KO WA 1 N o le waa ku ko le ri oye ile baba re je Oye jije A gbodo ni igboya 2 Faari aseju oko olowo […]
Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo 9 Eesan-an 10 Eewaa 11 Ookanla 10+1=11 12 Eejila 10+2=12 13 Eetala 10+3=13 14 Eerinla 10+4=14 15 Aarun din logun 20-5=15 16 […]
AWON LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN KAN TABI OMIIRAN NI ILE YORUBA NI WONYI, i Oya – pipe ii Esu – pipe iii Orin – arungba iv Ijala -sisun v Sango – pipe vi Iyere vii Ese – Ifa ESA – IFA / ORUNMILA: Awon olusi re ni babalowo […]
Akoto ni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia Alaafia Oloto Oloooto Dada Daadaa Eleyi Eleyii Marun Marun-un Alanu Alaaanu Ologbe Oloogbe […]
Litrreso alohun ni litireso ti a fi ohun enu gbe jade ti a jogun lati odo awon babanla wa. Apeere litireso alohun ajemayeye ni i Ekun Iyawo ii rara ii Bolojo iv Apepe v Dadakuada abbl Ekun iyawo gege bi litireso alohun ayeye Ekun Iyawo je ewi ti omo binrin ti n lo […]
Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin metodiisi, katoliki ati CMS se ipade lori akoto ede […]
Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I faweli nikan –(F) ii Apapo konsonati ati faweli (KF) iii Konsonati aranmupe asesilebu (N) […]
i ba – ta(shoe) (dd) – kf – kf ii E – we(leaf) (rd) – f – kf iii A– ja(dog) (rm) – f – kf iv Ba – ba (father)(dm) – kf – kf v Ti – ti(a name of a person) (mm) – kf – kf AMI OHUN LORI KONSONANTI ARAMUPE […]
Ami ohun ni o maa n fi iyato han laarin iro kan si iro keji. Ohun Isale \ (d) o doju ko opa osi Ohun aarin – (r) O wa ni ibu Ohun Oke / (m) O doju ko apa otun Ami Ohun lori faweli: A E E I O O U (Faweli airanmupe) […]
You cannot copy content of this page