AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN

Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si.

Isori oro Yoruba

  1. oro-oruko (NOUN)
  2. oro-aropo oruko (PRONOUN)
  • oro ise (VERB)
  1. oro Aropo afarajoruko (PROMINAL )
  2. oro apejuwe ( ADJECTIVE )
  3. oro atoku (PREPOSITION)
  • oro asopo ( CONJUCTION )

 

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: ISINKU

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku logan ti o ku titi di akoko ti a fi sin.

Orisi oku sinsin ni ile Yoruba

  1. Oku Oba
  2. Oku Ijoye
  • Oku Alaboyun
  1. Oku Adete
  2. Oku Abuke
  3. Oku Afin
  • Oku Odo
  • Oku Aro
  1. Oku eni ti o pokunso
  2. Oku eni ti sango pa
  3. Oku eni ti igi yalu pa abbl.

 

Ohun elo oku sin-sin.

  1. Aso funfun
  2. poosi oku/eni
  3. etutu lorisirisi
  4. owu tutu
  5. igi ora
  6. eepe (iyepe)
  7. lofinde oloorun
  8. Oniruuru nnkan ti enu n je, ileke owo, bata, opa itile abbl.

Igbelewon:

  • Fun asa isinku ni oriki
  • Ko orisi oku sin sin ni ile Yoruba mewaa
  • Ko ohun elo oku sin sin nile Yoruba
  • Ko isori oro ede Yoruba mefa

Ise asetilewa: fun awon isori oro wonyi loriki pelu apeere meji meji:

  1. Oro oruko
  2. Oro ise

 

See also

AROKO ATONISONA ALAPEJUWE

AWON LITIRESO APILEKO ERE-ONITAN

ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE

AKOLE ISE: ASA ATI OHUN ELO ISOMOLORUKO

AKOLE ISE: LITIRESO APILEKO

Acadlly