AMI OHUN
Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o… Read More »AMI OHUN
Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o… Read More »AMI OHUN
Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni;… Read More »IRO KONSONANTI
Iro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa… Read More »IRO FAWELI
Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro,… Read More »EYA ARA IFO
Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo… Read More »ORUNMILA
Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si. Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun, orisa ni Olorun da won, won… Read More »AWON ORISA ILE YORUBA
AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe. A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo + … Read More »ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE
Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.
Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo; O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi… Read More »AYOKA ONISOROGBESI
AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa… Read More »ORI-ORO | SILEBU EDE YORUBA
Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo… Read More »AROKO AJEMO ISIPAYA
Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu… Read More »Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun
Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. Ise Oro-Oruko Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun –… Read More »ISE ORO ORUKO ATI ORO AROPO ORUKO NINU GBOLOHUN
Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re. Aroko oniroyin je aroko ti o jo mo iroyin sise. Eyi le je kiko sile… Read More »AKOLE ISE- EDE: AROKO ATONISONA ONIROYIN (NARRATIVE ESSAY)
Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun… Read More »Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence)
Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya… Read More »Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati… Read More »Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi
Akaye: Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yei yekeyeke. Orisi ayoka ninu akaye Akaye oloro geere Akaye ewi Akaye oni isoro-n-gbesi… Read More »Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan… Read More »Ede:- Akaye oloro geere
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012 Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT) Ona ti a le gba dena ogun Ki ife… Read More »Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru