Yoruba

ORO – AYALO

Inu ede ti a ti n ya oro lo. Ona ti a n gba ya oro wonu ede Yoruba.   Akoonu Oro – ayalo -: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede miiran Oro – ayalo -: ni mimu oro lati inu ede kan wo inu ede […]

ORO – AYALO Read More »

AKORI EKO: ORO – ISE

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro

AKORI EKO: ORO – ISE Read More »

AKOLE ISE: Akoto ode-oni

Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin metodiisi, katoliki ati CMS se ipade lori akoto ede

AKOLE ISE: Akoto ode-oni Read More »

ASA IGBEYAWO

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional love)   IGBESE IGBEYAWO Ifojusode Iwaadi Alarina Isihun / ijohen Itoro Baba gbo, iya gbo

ASA IGBEYAWO Read More »

ASA ISINKU NI ILE YORUBA

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku. Ni ile Yoruba, ayeye isinku agba je ohun Pataki ti o fese mule ni awujo awon Yoruba paapaa ti o ba je agbalagba ti o fi owo rori ku. Inawo ati ipalemo oku maa n po fun awon molebi ati ana oku. Gbogbo molebi oku ti

ASA ISINKU NI ILE YORUBA Read More »

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko –

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA Read More »

AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.     Apeere apa silebu ni wonyi; APA ALEYE APEERE ORO APA (a)    Odo

AKOLE ISE: SILEBU Read More »

FONOLOJI EDE YORUBA

Foniimu konsonanti Foniimu faweli ati ohun Eda foniimu konsonanti ati faweli Akoonu (Iro aseyato) Foniimu ni awon iro ti o le fi iyato han laaarin oro kan tabi omiran Ap Foniimu ni /b/ /d/ /t/, eyi ti o tumo si pe  bi a ba fi iro kan dipo ikeji iyato yoo wa Ap Ede Ere

FONOLOJI EDE YORUBA Read More »