Categories
JSS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)

Akole Ise:  Ede – Aroko Alapejuwe

Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re

Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.

Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe

Akole Ise:  Ede – Aroko Alapejuwe

Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re

Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.

Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe

 1. Ile iwe mi
 2. Ilu mi
 3. Oja ilu mi
 4. Ounje ti mo feran
 5. Ile isin wa
 6. Ijanba oko kan ti o sele loju mi abbl.

Ilana to se Pataki fun aroko asapejuwe

 1. Yiyan ori oro
 2. Sise arojinle ero lai fi kan bokan ninu
 • Sise apejuwe oro la see se sinu iwe ni ipin afo (paragraph) kookna.

 

Igbelewon :

 1. Kin ni aroko
 2. Fun aroko asepejuwe ni oriki
 • Ko ori ora aroko asapejuwe marun-un

 

Ise asetilewa:-yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012)  Oju Iwe ketadinlogbon Eko kerinla

 

ASA:-  Asa Iran-ra-eni lowo ni ile Yoruba

Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba e ni asiko pipe.

Ona iranra-eni lowo ni aye  atijo eti ni ode oni ni wonyi :-

 1. Esusu
 2. Ajo
 • Awe
 1. Aaro
 2. Arokodoko
 3. Egbe alafowosowopo

Igbelewon :

 1. Salaye asa irara-eni lowo
 2. So iyato to wa laarin awon wonyi
 3. Esusu ati ajo
 4. Owe ati aaro

 

Ise asetilewa:-  yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012)  Oju Iwe kokandinlogbon Eko kerindinlogun

 

LITIRESO:-  IWE KIKA – ERE ONISE

 See also

AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE

Eto ise fun saa keji

ASA IGBEYAWO

AKORI EKO: EYAN

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Acadlly

You cannot copy content of this page

error: Content is protected !!