Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya… Read More »Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya… Read More »Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati… Read More »Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi
Akaye: Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yei yekeyeke. Orisi ayoka ninu akaye Akaye oloro geere Akaye ewi Akaye oni isoro-n-gbesi… Read More »Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan… Read More »Ede:- Akaye oloro geere
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012 Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT) Ona ti a le gba dena ogun Ki ife… Read More »Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru
Aroko atonisona asotan ni aroko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju wari tabi awon ise ti a gbo lenu enikan Ilana Fun Kiko Aroko Oniroyin… Read More »Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)
AKOLE ISE:- Ede:- Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori… Read More »OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)
Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe
Aroso alapejuwe ni sise apejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to sele gege bi a se rii g an-an pelu ohun enu. Aroso ni ki si ni akosile ohun enu ni… Read More »AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE
Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye) Ose keji: Ede… Read More »Eto ise fun saa keji
Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo Sipele Ode Oni Iddo Ido Otta Ota Jebba Jeba Offa Ofa Ebute-Metta Ebute-Meta Ottun Otun Shagamu Sagamu… Read More »AKOLE ISE: Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni
AKOLE ISE: Igbagbo Yoruba Nipa Orisirisi Oruko Ile Yoruba. Igbagbo Yoruba ni pe “ile la n wo ki a to so omo loruko”. A kii dede fun omo ni oruko… Read More »AKOLE ISE: KIKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN
Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni… Read More »AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE
Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise… Read More »AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE
Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta Figo 300 Oodunrun 305 Oodunrun ole-marun-un 310 Oodunrun ole-mewa 315 Okooleloodunrun odunarun-un 320 Okooleloodunrun 325 Okooleloodunrun ole-marun-un 330 Okooleloodunrun ole-mewaa 335 Ojileloodunrun odin marun-un… Read More »Akole ise: onka Yoruba (300-500)
Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati… Read More »Onka Yoruba (101 – 300)
Litireso je ona ti Yoruba n gba lati fi ero inu won han lori ohun ti a je koko tabi iriri aye won. ISORI LITIRESO Litireso alohun Litireso apileko Litireso… Read More »LITIRESO ALOHUN TO JE MO AYEYE
AWON ISE AKANSE ILE YORUBA Eni hihun Ikoko mimu Irin riro Aro dida Igba finfin abbl. Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba. ISE IKOKO MIMO: ise ikoko… Read More »AWON ISE AKANSE ILE YORUBA
Igbelewon : Kin ni gbolohun onibo? Ko isori gbolohun onibo Salaye asa igbeyawo ode-oni lekun-un-rere Ise asetilewa: Gege bi esin re, salaye ilana igbeyawo ode-oni OSE KERIN EKA ISE: … Read More »Kika Iwe Apileko Oloro Geere Ti Ijoba Yan
Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo… Read More »EYA GBOLOHUN