Mr. Shodiya

Yoruba

AMI OHUN

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa …

AMI OHUN Read More »

Yoruba

IRO KONSONANTI

Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, s, t, w, y. APEJUWE IRO KONSONANTI AKOONU Iro Konsonanti: ni iro …

IRO KONSONANTI Read More »

Yoruba

IRO FAWELI

Iro-Ede -; ni ege ti  o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti …

IRO FAWELI Read More »

Yoruba

EYA ARA IFO

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.   EYA ARA IFO EYA ARA IFO …

EYA ARA IFO Read More »

Yoruba

ORUNMILA

Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n …

ORUNMILA Read More »

Yoruba

AWON ORISA ILE YORUBA

Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si.  Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun,  orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa ipin keji ni awon eniyan ti a so di orisa nitori ise  ribiribi owo won …

AWON ORISA ILE YORUBA Read More »

Yoruba

ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE

AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe.  A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo  +          kobo   =          kobokobo Odun  +          odun   =          odoodun Ale      +          ale       =          alaale Osu     +          osu      =          osoosu Osan   +          osan    =          osoosan Egbe   …

ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE Read More »

Yoruba

ISEDA ORO-ORUKO

Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi  a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.

Yoruba

AYOKA ONISOROGBESI

Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo;               O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si  egbe wa. Baba Ramo     Haa! E seun o. Mo dupe o. Ayo                 Sugbon owo iwegbe re n ko- …

AYOKA ONISOROGBESI Read More »

Yoruba

AROKO AJEMO ISIPAYA

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Ise ti mo fe lojo iwaju. Ki …

AROKO AJEMO ISIPAYA Read More »

Yoruba

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi

Salako:-         Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:-        Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:-                       Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :-        Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o Adunmi :-      Bi o se emi ati ile mi, buburu kan …

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi Read More »

Yoruba

Ede:- Akaye oloro geere

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:-  Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba ni lasiko. Ipa Ti Asa Iranra-Eni Lowo N Ko Ninu Ise Ajumose At …

Ede:- Akaye oloro geere Read More »

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly