Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba

Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade.

Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun.

Orisi eya gbolohun ti o wa ninu ede yoruba

  • Gbolohun abode
  • Gbolohun ase
  • Gbolohun ibeere
  • Gbolohun alaye
  • Gbolohun iba/kari
  • Gbolohun ayisodi
  • Gbolohu akiyesi alatenumo
  • Gbolohun asoduruko
  • Gbolohun alakanpo abbl.
  • Gbolohun Abode (Simple Sentence):- Eyo oro ise kan ni gbolohun yii maa n ni bee ni kii gun.

Mo ra isu

Ayomide rerin-in

  • Gbolohun ase:- Gbolohun yii ni a n lo lati fi pase fun eni ti an ba soro.  Apeere;

E dide jokoo

Wa ri mi

Da ke je

  • Gbolohun ibeere:- Eyi ni lilo awon wunren ibeere lati fi se ibeere.  Atoka bi, tani, ki ni, ba wo, me loo, nje, sebi abbl. Ni a n lo lati fi se ibeere.  Apeere;

Se Olu wa?

Ta ni o jale?

  • Gbolohun alaye:- Eyi ni a fi n se iroyin bi isele tabi nnkan se ri fun elomiran lati gbo.  Apeere

Ise ojo oni ti pari

Mo lo si ilu oba losu to koja

  • Gbolohun alakanpo :- Gbolohun yii ni a maa n fi oro asopo so awon gbolohun miran po di eyo gbolohun kan.  Oro asopo bii, ati, sugbon, omo, tabi, abbl.

ni a n lo lati fi kan gbolohun meji po.  Apeere ;

kunle ati olu lo si oja

abike jeun sugbon ko yo abbl.

Igbelewon :-

  1. Fun gbolohun ni oriki
  2. Irufe gbolohun wo ni wonyi ?
  3. Se o daa bee?
  4. Ade ra eja
  5. Pe e wa dun mo wa ninu
  6. A ko tii lo
  7. Bola lo sugbon ko baa

Ise Asetilewa:-  yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012)  Oju Iwe kejila Eko kefa

 

Asa:-  Asa Iwa Omoluabi

Iwa lewa, bee si ni iwa rere ni eso eniyan.  Iwa eniyan a maa fi eniyan han, iru eni ti eniyan je nitori « eefin niwa ».

Ojuse Omoluabi Si Obi

  1. Kiki awon obi ni gbogbo akoko
  2. Jije ise fun obi ni gbogbo igba
  3. Mimo riri ati iyi obi
  4. Gbigba ati titele imoran rere lati enu awon obi
  5. Bibu ola fun an obi ni gbogbo igba

Ojuse Omoluabi Si Ijoba/Awujo

  1. Sise imototowo ayika
  2. Pipa ofin ati ilana agbegbe tabi orile ede mo
  3. Jije olododo ninu ise eni
  4. Sisan owo ori fun ijoba lati pese ohun amayederun
  5. Lilowo ninu ise ajumose lawujo

 

Igbelewon:-

  1. Ko ojuse omoluabi si obi marun-un
  2. Ojuse omoluabi ko kere ni awujo ko ojuse omoluabi merin si ijoba.

 

Ise Asetilewa

  1. Okan lara awon iwa omoluabi ni __________ (a) oro siso  (b) ounje jije  (d) i se sise
  2. Ise ati iwa omoluabi bere lati ______ (a) inu ile  (b) ile iwe  (d) ile iwosan
  3. Ki ni omoluabi gbodo se fun awon obi ________ (a) bu obi  (b) na obi  (d) bowo fun obi
  4. Bi omoluabi ba ri agblagba ti o ru eru, o gbodo __________ iru eni bee lowo (a) je  (b) ran  (d) bu
  5. Imototo lo le ________ aarun gbogbo  (a) bori  (b) gbe  (d) segun

 

LITRESO- KIKA IWE TI IJOBO YAN

See also

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi

Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi

Ede:- Akaye oloro geere

Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru

Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350
Acadlly