Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012

Asa:-  Ogun Jija (WAR/CONFLICT)

Ona ti a le gba dena ogun

  1. Ki ife ti o gbona wa laarin awon ara ilu
  2. Ki asoye tabi agboye naa wa laarin ara ilu
  3. Ni gba tie de ayede ba be sile eemi suuru se koko
  4. Nini emi idariji
  5. Ibowo fun omolakeji eni
  6. Iwa pele abbl.

Aleebu Ogun Jija

  1. Ogun maa n da ote si le laarin ilu meji
  2. Ogun a poju maa n fa iyan
  3. O maa n pa ilu run
  4. Gbogbo ohu amayederun ilu yoo denu kole
  5. O maa n fa airisese
  6. Ipadanu emi ati dukia maa n po ni akoko ogun abbl.

Anfaani Ogun Jija

  1. Ogun jija je ona ti a fi n da abo bo ilu lowo ote
  2. O n mu ki ilu wa ni imura sile ni gbogbo igba
  3. Ogun jija n mu ni mo o le ati alagbara ilu
  4. O n je ki a mo bi ilu eni se ni agbara ogun jija si.

 

Igbelewon :-

  1. Ko orisi ona marun-un ti a le gba dena ogun
  2. Ko aleebu ogun jija merin-in
  • Anfaani wo ni ogun jija n se fun ilu

 

Ise Asetilewa  :-  Gbiyanju gege bi akekoo ede Yoruba lati gba aare orile-ede yii ni iyanju lori ona ti o le gba segun ogun agbesumobi (boko haram) ti o n yo orile ede wa yii lenu lati ojo to ti pe

 

LITERSO:- Kika iwe apileko ere onise ti ijoba yan.

See also

Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)

OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)

OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)

AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE

Eto ise fun saa keji

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350