AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE

Aroso alapejuwe ni sise apejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to sele gege bi a se rii g an-an pelu ohun enu.

Aroso ni ki si ni akosile ohun enu ni a fi n se apejuwe isele naa.

Apeere ori oro aroso alapejuwe

a.Oluko mi

b.Onje ti mo feran

d.Oja ilu mi

e.Ile iwe mi abbl.

Ilana to se pataki fun aroso alapejuwe

  1. Yiyan ori-oro
  2. Sise arojinle ero lai fi kan-nokan ninu
  • Sise apejuwe ero lokan-e-jokan.

 

Igbelewon: (i) So itumo aroso alapejuwe

(ii) Ko ori oro meji ti o je mo aroso alapejuwe

(iii) Ko liana meta ti a gbodo tele ti a ba n so sapejuwe isele

(iv) Se opejuwe ile iwe re pelu ohun enu.

 

Ise-asetilewa : Se apejuwe ile iwe re pelu ohun enu

 

Asa : Asa iranra-eni-lowo ni ile yoruba

Iranra eni-lowo je ona ti yoruba n gba lati ran ara won lowo nibi ise won gbogbo.

Orisirisi ona ti yoruba n gba ran ara won lowo laye ati jo

  1. Owe
  2. Ajo
  • Aaro
  1. Arokodoko
  2. Esusu
  3. Owe: Omo knrin ti o ba ti ni iyawo ni o maa be awon ore re lowo lati ba a sise.

Awon ise ti a le be owe se

  1. Ile kiko
  2. Sise ise oko abbl
  3. Ajo:- O je ona dida owo jo po ni mejimeji tabi ju bee lo.  Eniyan le gba ju iye ti o ba da lo.
  • Aaro :- Eyi tunmo si bamiro teni, ki n ba o ro tire ».  awon enyan merin si marun-un ti oko won ba wo nitosi ara won ni won maa n se aaro  nipa sisise n ioko enikookan
  1. Arokodoko :- Awon ore meji ti oko won ko jinna sira le jo maa ba ara sise.Eyi tunmo si pe bi won ba sise Taye ni aaro won yoo lo si oko kehinde ni osan.  Asa riro oko kiri yii ni a n fe ni a-ro-oko-de-oko.
  2. Esusu :- O je asa kikora jopo ati da owo je ni aye atijo lati ran ora eni lowo.  Eye ti eniyan ba da ni yoo ko  ni abe akoso awon olori egbe.

Igbelewon :-

  1. Ko itumo ireanra-emi lowo
  2. Daruko orisirisi ona ti a n gba lati ran ara eni lowo laye atijo
  • Salaye awon ona wonyi ni soki

Ise Asetilewa:-  Simplified Yoruba li workbook for Basic 8 (Jss2) lati owo Adewoyin S. Y. Page 63-64.

 

Litireso:-  Ewi alohun to je mo esin ibile

Awon ewi alohun ajemo esin ibile ati orisa ti a n lo won fun ni yi:-

Ewi                             Orisa

  1. Esa-pipe Egungui
  2. Esu-pipe Esu
  • Sango-pipe Sango
  1. Oya-pipe Oya
  2. Ijale-sisun Ogun
  3. Iyere Ifa                   Orunmila

 

  • Orin Arungbe Oro

 

Ijala:–  Akoko odun ogun ni won n sun ijala.  Awon olusin re ni ;

  1. Ode
  2. Agbe
  3. Alagbede ati awon onise irin gbogbo

IWULO IJALA SISUN

  1. Won n lo o lati fi yin ogun
  2. Lati fi ki oriki agba ode
  • Lati fi so iriri ode ninu igbo

Ounje ogun:Aja, iyan, obi, emu, akuko adie abbl.

Eewo:-  Gbibe ofifo agbe duro

Esa-pipe:-  Akoko odun egungun ni won maa n pe esa.  Awon oje,elegun ni won maa n pe esa.

Ounje egungun

Olele, emu, obi, agbo.

Eewo :-  Eegun ko gbodo subu.

Orin Arungbe:-  Akoko odun oro ni won maa n ko orin arugbe.

Ounje oro

Emu, aja

Eewo

  1. Obinrin ko gbodo ri oro
  2. A kii ru ajeku oro

Iyere Ifa:-  Akoko odun ifa ni won ma n sun iyere ifa.  Awon babalawo ni llusin re.

Ounje ifa

Adie, ewure, eyele, igbin, ejea, epo

Eewo:-  Jije isu tit un saaju odun

 

Igbelewon :

  1. Ko ewi alohun ajemo esin ibile marun-un pelu orisa ti a n lo won fun
  2. Salaye meji père lekun un rere

Ise Asetilewa :-   mu okan pere lara ewi alohun ajemesin ti o mo ki o si salaye lekun un rere

 

See also

Eto ise fun saa keji

ASA IGBEYAWO

AKORI EKO: EYAN

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350