Eto ise fun saa keji

Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500)

Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko)

Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye)

 

Ose keji: Ede aroso alapejuwe

Asa-asa iranra-ero lowo

Litireso-ewi alohun to je mo esin ibile – ijala – iremoje – iyere ifa – ese/iwi – egungun

 

Ose keta: Ede aroko alapejuwe (kiko aroko)

Asa-asa iranra-eni-lowo ni ile yoruba

Litireso – iwe kika-ere onise

 

Ose-kerin: Ede aroso asotan/oniroyin (ilana bi a se n ko o)

Asa-asa ogun jijo

Litireso-litireso apileko (kika iwe ere orise ti ijoba yan)

 

Ose karun-un: Ede aroko asotan/oniroyin (kiko aroko)

Asa-ogun jija

Litireso-ewi alohun to je mo esin ibile

 

Ose kefa: Ede – akaye oloro geere/weeru

Asa-ogun jija

Litireso-kiko iwe apileko ere onise ti ijoba yan

 

Ose keje: Ede-akaye oloro geere

Asa-atunyewo asa iranra eni lowo

Litireso-kiko iwe apileko ti ijoba yan

 

Ose kejo: Ede ilana kika akaye onisorongbesi

Asa-asa ikini I

Litireso-kika iwe itan

Apileko ere-onise ti ijoba yan

 

Ose kesan-an: Ede akaye onisorogbesi

Asa-asa iwa omoluabi

Litireso-kika iwe apileko ti ijoba yan

 

Ose kewa: Ede-atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba

Asa-asa iwa omluabi

Litireso-kika iwe litireso apileko ti ijoba yan.

 

See also

ASA IGBEYAWO

AKORI EKO: EYAN

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350
Acadlly