ASA IGBEYAWO

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba.

Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni

  1. Ifesona (courtship)
  2. Ifayaran (perseverance)
  3. Suuru (patience)
  4. Ipamora (tolerance)
  5. Igbora-eni-ye (understanding)
  6. Ife aisetan (unconditional love)

 

IGBESE IGBEYAWO

  1. Ifojusode
  2. Iwaadi
  3. Alarina
  4. Isihun / ijohen
  5. Itoro
  6. Baba gbo, iya gbo
  7. Idana
  8. Ipalemo
  9. Ifa iyawo
  10. Ojo igbeyawo
  11. Ese iyawo wiwe
  12. Ibale
  13. Ikorun
  14. Ojo keje

IRO KONSONANTI

Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun jijade eemi ni kaa enu nigba ti a ba n pe won. Ona meta ni a le gba mo iru iro konsonanti ti an pe. Awon ona wonyii ni:

  1. Ibi isenupe
  2. Ona isenupe
  3. Abuda iro konsonanti
  4. IBI ISENUPE: orisii mejo ni ibi isenupe iro konsonati ede Yoruba. Awon ibi isenupe wonyi bere lati ete lo si ibi otooto orule enu titi lo dopin. Awon naa ni:

(i) Afetepe

(ii) Afeyinfetepe

(iii) Aferigipe

(iv) Afajaferigipe

(v) Afajape

(vi) Afafasepe

(vii) Afafase fetepe

(viii) Afi-tan-an-na-pe

 

  1. ONA ISENUPE: orisii meje ni awon ana isenupe iro konsonanti awon ni won wa lori bi afefe eemi ti maa n jade nigba ti a ba n pe iro tabi soro. Awon ni:
  2. Asenupe
  3. Afunnupe

iii. Asesi

  1. Aranmupe
  2. Arehon
  3. Afegbe enupe

vii. Aseesetan

 

  1. ABUDA IRO KONSINANTI: ti a ba fe se apejuwe iro konsonanti ni ilana abuda, a ni lati wa awon ilana yii:
  2. Orisun eemi (eemi amisinu tabi eemi amisode)
  3. Ipo ti alafo tan-an-na wa (ipo imi tabi ipo ikun)

iii. Ipo afase (boya afase wa sile tabi o gbera soke)

  1. Irufe afipe ti a lo (yala afipe asunsi tabi akanmole)
  2. Irufe idiwo ti o wa fun eemi (boya ona se patapata tabi o si sile die)

 

See also

AKORI EKO: EYAN

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI

ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350