JSS 3 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

ASA IGBEYAWO

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional love)   IGBESE IGBEYAWO Ifojusode Iwaadi Alarina Isihun / ijohen Itoro Baba gbo, iya gbo

ASA IGBEYAWO Read More »

AKORI EKO: EYAN

Eyan ni awon wunren (oro) ti a fi n yan oro – oruko (noun) tai apola oruko (Noun phrase) ninu gbolohun tabi ninu isori. Bi apeere: Iwe tuntun ni a f era Aso ala ni mo wo ‘Tuntun’ ati ‘ala’ ti a fa ila si ninu gbolohun oke yii ni oro eyon ti o n

AKORI EKO: EYAN Read More »

AKORI EKO: ERE IDARAYA

Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba dile tabi awon eniyan ba dari bo lati ibi ise oojo won ni won maa

AKORI EKO: ERE IDARAYA Read More »

Acadlly