ASA ISINKU NI ILE YORUBA

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku. Ni ile Yoruba, ayeye isinku agba je ohun Pataki ti o fese mule ni awujo awon Yoruba paapaa ti o ba je agbalagba ti o fi owo rori ku.

Inawo ati ipalemo oku maa n po fun awon molebi ati ana oku. Gbogbo molebi oku ti o wan i irinajo ati ti itosi ni won gbodo peju pese si ibi isinku naa.

Igbese Isinku ni ilu Yoruba

 1. Itufo ikede
 2. Ile oku gbigbe
 3. Wiwe oku
 4. Oku tite
 5. Oku sinsin
 6. Igbalejo

Iranse olodumare ni iku je. Oun ni Adebola maa n ran lati mu eniyan ti akoko to da ba to lo si orun. Awon Yoruba gbagbo wipe gbese ni iku, ko si eda ti ko ni san-an. Won ni “Aye” ni oja orun ni ile. Irinajo ni awon Yoruba ka iku si. Idi niyi ti won fi maa n sin awon nkan jije, mimu aso ati bata mo oku agba ki o le ri nkan lo ni irinajo aye. Awon oba ni ile Yoruba tile maa n ni abobak ti yoo maa ran-an lowo ni ona orun.

Ise Asetilewa

 1. Eni ti ara san pa
 2. Eni ti o pokunsi
 3. Oku abuke
 4. Oku aboyun
 5. Oku onigbese

 

See also

FONOLOJI EDE YORUBA

AKOLE ISE: AROKO KIKO

AKOLE ISE: AKOTO EDE YORUBA

AKOLE ISE: SILEBU

AKOLE ISE

3 thoughts on “ASA ISINKU NI ILE YORUBA”

Average
5 Based On 2

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly