AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso

Batani / Ihun Silebu

Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.

 

 

Apeere apa silebu ni wonyi;

APA ALEYE APEERE ORO APA
(a)    Odo

Silebu

Eyi ni ipin ti a maa

n gbo julo ti a ba pa silebu sita. Iro faweli tabi konsonanti aranmupe asesilebu ‘n’ ni won le duro bii odo silebu

 

I – le

 

I – tan

 

Du-n-du

 

‘I’ ati ‘e’

 

‘I’ ati ‘on’

 

‘U’, ‘n’ ati ‘u’

(b)   Apaala Eyi ni awon iro ti a kii gbo kete kete ti a ba pe oro sita I – we

I – tan

Du-n-du

‘w’

‘t’

‘d’ ati ‘d’

(c)    Abere silebu Eyi ni iro ti o bere silebu ninu ihun. O le je faweli tabi konsonanti Kan – ge

I – we

I – le

‘k’ ati ‘g’

‘I’ ati ‘w’

‘I’ ati ‘I’

(d)   Apekun silebu Eyi ni iro faweli ti o pari silebu Wa

Je

Kun

‘a’

‘e’

‘un’ abbl.

 

EYA IHUN SILEBU

Eya ihun silebu meta ni ede Yoruba ni . Eya ihun naa ni wonyi;

  1. Ihun eleyo faweli (f)
  2. Ihun akanpo konsonanti ati faweli (kf)
  • Ihun eyo konsonanti aranmupe ase silebu (n)

Faweli airanmupe faweli aranmupe le duro bi silebu kan apeere;

Mo ri i

Mo ra a

Ran – an

Fun – un abbl

Apapo konsonanti ati faweli leje silebu kan soso apeere;

  • Ke k – e
  • Je j – e
  • Fe f – e
  • Gba gb – a
  • Sun s – un

Eyo konsonanti aranmupe ase silebu le da duro bii silebu apeere;

  • Ko m ko – ko – n-ko
  • Gbangba – gba – n-gba
  • Ogedengbe – o – ge – de – n-gbe
  • Gbanjo – gba – n-jo abbl.

 

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: AWON OWE TI O SUYO NINU ISE ATI ISE YORUBA

Oniruuru owe ni awon agba n lo gege bii oro ijinle ogbon lari pe akiyesi ede si ohun ti o wa ni ayika won tabi lati ronu jinle.

  • Owe to je mo iwa ati ise ede eniyan ni woyi;
  1. Omo ti a fi ise wo ni degba omo ti a fi oju ojo bi ko to gege
  2. Ogun omode ku sere gba ogun odun
  • Eni roar pa eere, yoo rifun re
  1. Woso de mi ko le dabi oniso, n o se bi iya ko le jo iya to bi ni lomo.
  • Owe to je mo ise ni wony i-

     ise agba

  1. Ila kii ga ju onire lo
  2. A kii gbin alubosa ko hu efo
  • Iti ogede ko to ohun a a pon ada si

Ise ode

  1. Kin ni kan lo ba ajao je, apa re gun ju itan lo
  2. Kaka ki kiniun se akapo ekun, olukuluku yoo se ode re lotooto ni
  • Awodi oke ko mo pe ara ile n wo oun
  1. Obo n jogede, obo n yundi, obo ko mo pe ohun to dun lo n pa ni

(D)    Owe to jemo onsowo tabi owo sise

  1. Kin ni iya alaso n ta to yo egba dani, abi ewure n je leesi ni
  2. Ona kan ko wo oja

iii.    Eni ti a n ba na oja ni a n wo,  a kii wo ariwo oja.

Igbelewon:

  • Fun silebu loriki
  • Salaye batani silebu inu ede Yoruba
  • Ko eya ihun silebu pelu apeere
  • Ko owe ti o suyo ninu ise ati ise Yoruba

 

Ise asetilewa:  ko owe ti o je mo meji lara ise abinibi ile Yoruba

 

See also

AKOLE ISE

AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350