AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka.

Orisi aroko ti o wa niyi;

 1. Aroko oni leta
 2. Aroko onisorogbesi
 • Aroko alariyanyan
 1. Aroko alapejuwe
 2. Aroko ojemo – isipaya
 3. Aroko atonisona asotan
 • Aroko oniroyin

Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko

 • Yiyan ori-oro: A ni lati fa ile tere si ebe ori-oro ti a n ko aroko le lori
 • Sise ilepa ero: A ni lati ronu jinle ki a si to ero wa kale ni okookan ninu ipinro kookan
 • Kiko aroko: Ifaara ko gbodo gun ju o si gbodo ba akoko mu.
 • Ipinro: Akoto ode-oni se Pataki ni ipinro kookan bii afiwe, owe, akanlo ede abbl.
 • ILO-EDE: Ojulowo ede se Pataki ninu aroko
 • IGUNLE/IKADi: Eyi ni ipin afo ti o pari aroko o gbodo se akotan gbodo koko, ero ati ori oro ti a yan.

 

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: ISE ABINIBI ILE YORUBA

Ise abinibi/isenbeye ni ise iran ti a jogun lati owo awon baba nla wa.

Iran kookan ni o ni ise abinibi ti a mo ti o si f ease-file omo lowo. Yoruba lodi si iwa ole, lati kakore ni won si ti maa n ko awon omo won ni ise abinibi won. Ni geere ti a ba ti bimo ni awon obi re yoo ti da ifa akosejaye lati mo iru ise ti ele daa yan fun omo naa. Awon ise abinibi  Yoruba niwonyi;

Awon ise isembaye Yoruba ni wonyi;               

 • Ise Agbe
 • Ilu lilu
 • Ikoko mimo
 • eni hihun
 • aro dida
 • Ise ode
 • Ise onidiri
 • Ise akope
 • Ise Alagbede
 • Ise ona bii;
 • Ona igi
 • Ona okuta
 • Ona awo

 

EKA ISE: LITIRESO

AKOLE ISE: ITUPALE ASAYAN IWE LITIRESO APILEKO TI AJO WAEC /NECO YAN.

Igbelewon :

 • Fun aroko ni oriki
 • Ko orisi aroko mefa
 • Salaye awon ilana ti alaroko yoo fi sokan bi o ba n ko aroko
 • Kin ni ise isembaye/
 • Ko awon ise isembaye ile Yoruba

Ise aetilewa: mu okan lara ise isembaye ile Yoruba ki o si salaye lekun-un-rere

 

See also

AKOLE ISE: AKOTO EDE YORUBA

AKOLE ISE: SILEBU

AKOLE ISE

AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly