AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

Apejuwe  iro konsonanti

Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi gbe won jade.

A le pin iro konsonanti si ona wonyi;

  1. Ibi isenupe
  2. Ona isenupe
  • Ipo alafo tan-an-na

Ibi isenupe: Eyi ni ogangan ibi ti a ti pe iro konsonanti ni enu. O le je afipe asunsi tabi akanmole.

 

Alaye lori ibi isenupe

IBI ISENUPEKONSONANTI TI A PEISESI AFIPE
Afeji-ete-peB, mEte oke ati ate isale pade-apipe akanmole ati asunsi pade
Afeyin fetepeFEte isale ati eyin oke pade afipe asunsi ati akanmole pade
AferigipeT, d,s,n,r,lIwaju ahon sun lo ba erigi oke . afipe asunsi ati afipe akanmole
Afaja ferigipeJ,sIwaju ahon sun kan erigi ati aarin aja enu. afipe ati afipe
AfajapeYAarin ahon sun lo ba aja enu.  afipe asunsi ati akanmole
AfafasepeK, gEyin ahon sun lo kan afase .afipe asunsi ati akanmole
AfafasefetepeKp, gb,wEte mejeji papo pelu eyin ahon kan afase . afipe asunsi ati afipe akanmole
Afitan – an-na – peHInu alafo tan-an na ni a fi pe e

 

Ona isenupe: Eyi  toke si iru idiwo ti awon afipe n se fun eemi ti a fi pe konsonanti, ipo ti afase wa ati iru eemi ti afi gbe konsonanti jade.

 

 

 

Alaye lori ona isenupe

ONA ISENUPEKONSONANTI TI A PEIRU IDIWO TI AFIPE SE FUN EEMI
AsenupeB,t,d,k,g,p,gbKonsonanti ti a gbe jade pelu idiwo ti o po julo fun eemi afase gbe soke di ona si imu awon afipe pade lati so eemi, asenu ba kan na ni eemi inu enu ro jade nigba ti a si
AfunnupeF,s,s,hAwon afipe sun mo ara debi pe ona eemi di tooro, eemi si gba ibe jade pelu ariwo bi igba ti taya n yo jo
AsesiJA se afipe po, eemi to gbarajo ni enu jade yee bi awon afipe se si sile
AranmuM,nAwon afipe pade lati di ona eemi, afase wale, ona si imu le, eemi gba kaa imu jade
ArehonRAhon kako soke ati seyin, abe iwaju ahon fere lu erigi, eemi koja lori igori ahon
Afegbe-enu-peIOna eemi se patapata ni aarin enu, eemi gbe egbe enu jade
AseesetanW,yAwon afipe sun to ara, won fi alafo sile ni aarin enu fun eemi lati jade laisi idiwo

 

Ipo tan-an-na: ibi alafo tan-an-na ni a fi n mo awon iro konsonanti akunyun ati aikunyun.

Alaye ni kikun

IRO KONSONANTIALAYE
Konsonanti akunyunD,j,gb,m,n,r,l,y,wAwon konsonanti  ti a gbe jade nigba ti alafo tan-an-na wa ni ipo ikun, eemi kori Aaye koja,eyi fa ki tan-an-na gbon riri
Konsonanti aikunyunP,k,f,s,s,h,tEyi ni awon konsonanti ti a gbe jade nigba ti alafo tan-an-na wa ni ipo imi eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woo rowo

 

ATE IRO KONSONANTI

Ona isenupe Afeji-

Etepe

Efeyin-

fetepe

Aferi-gipeAfaja- ferigipeAfaja-peAfafa-

sepe

Afafaseu

Fetepe

Afitan-an-na pe
AsenupeAkunyunBDGGb
AikunyunTKKp
AfunnupeAikunyunFSSH
AsesiAkinyunDz
AranmuAkinyunMN
ArehonAkinyunR
Afegbe-

Enupe

AkunyunI

I

AseesetanAkunyunJW

 

See also

EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

EKA ISE: EDE

EKA ISE: EDE

Didaruko Faweli

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly