Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko atonisona asotan Aroko oniroyin Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko Yiyan ori-oro: A […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: AKOTO EDE YORUBA

Akoto ni sipeli tuntun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati fi maa ko ede Yoruba sile. Awon ayipada ti o de ba kiko ede Yoruba sile ni wonyi SIPELI ATIJO SIPELI TUNTUN IFIYESI Aiya Aiye Eiye Aya Aye Eye A gbodo yo faweli “I” nitori a ko […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.     Apeere apa silebu ni wonyi; APA ALEYE APEERE ORO APA (a)    Odo […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN)

Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro. Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji; Iro ohun geere Iro ohun eleyoo Iro ohun geere: Eyi ni iro ohun ti o duro ni ori silebu lai ni eyo rara. Awon iro bee ni; Iro ohun oke ( […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA

Ouje ni awon ohun ti eniyan ati aranko n je tabi mu ti o fun ara wa ni okun ati agbara. Won ni “Bi ebi ba kuro ninu ise, ise buse. Ouje ni oogun ebi. Ise Agbe ni ise ti o gbajumo julo ni ile Yoruba, awon agbe yii ni on pese ire-oko ti eniyan […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

Apejuwe  iro konsonanti Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi gbe won jade. A le pin iro konsonanti si ona wonyi; Ibi isenupe Ona isenupe Ipo alafo tan-an-na Ibi isenupe: Eyi ni ogangan ibi ti a ti pe iro konsonanti ni enu. O le je afipe asunsi tabi […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN

Ere – onise –  ese/iwi egungun , ijala Oriki itan isedele tabi eyi to n so idi abajo litireso atenudenu Yoruba ni eyi, awon ohun ti o n suyo nibe ni oriki itan isedale ati awon asa ajogunba Yoruba. Kiki ati kike je okan lara igbadun litireso atenudenu. Awon itan isedala ti a maa n […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA Apejuwe iro faweli A le sapejuwe iro faweli ni ona merin wonyi; Ipo ti afase wa Apa kan ara ahon to gbe soke ju lo ninu enu Bi apa to ga soke naa se ga to ninu enu Ipo ti ete wa Ipo ti afase wa: Afase […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

EKA ISE: EDE

Akole ise: Itesiwaju lori eko iro ede Yoruba. Iro ede ni ege ti o kere julo ninu oro eyi ti a le gboninu ede. Orisi iro meta ti o se Pataki ninu ede Yoruba ni, a.iro konsonanti iro faweli iro ohun Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eeni ti a fig […]

Categories
SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e […]

Acadlly

You cannot copy content of this page

error: Content is protected !!