AKOLE ISE: SILEBU
Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I faweli nikan –(F) ii Apapo konsonati ati faweli (KF) iii Konsonati aranmupe asesilebu (N) …