Yoruba

AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko atonisona asotan Aroko oniroyin Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko Yiyan ori-oro: A …

AKOLE ISE: AROKO KIKO Read More »