EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN

Ere – onise –  ese/iwi egungun , ijala

  1. Oriki itan isedele tabi eyi to n so idi abajo litireso atenudenu Yoruba ni eyi, awon ohun ti o n suyo nibe ni oriki itan isedale ati awon asa ajogunba Yoruba.
  2. Kiki ati kike je okan lara igbadun litireso atenudenu. Awon itan isedala ti a maa n ba pade ninu litireso atenudenu maa ran ni leti orirun ibi ti awon eniyan kan ti se, ti o si n je ki a ni ife sii daadaa.
  3. Ba kan naa, awon itan idi abajo , bi ori igun se pa, idi ti oju orun fi jinna si ile , idi ti a fi n bo oku mole abbl ni a maa n ba pade ninu litireso atenudenu.
  4. Eko ati ogbon: onirunru eko ni a maa n ba pade ninu litireso atenudenu , o maa n fi oye awon ohun ti o ye ki a maa se ati eyi ti ko ye ki a hu niwa han ni.
  5. Ikorajopo, idaraya, ipanilerin ati tita-opolo ji po jatirere ninu litireso atenudenu lati gbe asa Yoruba laruge.

 

Igbelewon:

  • Sapejuwe iro faweeli ni ona merin
  • Fun owe ni oriki
  • Salaye orisi owe pelu apeere
  • Ko igbadun ti o wa ninu litireso alohun ere onise

 

Ise asetilewa:    1. salaye awon owe wonyi  gege bi o ti ye o si pelu apeere irufe owe bee meji meji

  1. owe imoran
  2. Owe ibawi
  • Owe ikilo

 

See also

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

EKA ISE: EDE

EKA ISE: EDE

Didaruko Faweli

OSE KESAN-AN

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350