AKORI EKO: ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA

Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni pe iye ibi ti ohun bat i jeyo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu ti oro naa ni han. Iro meta ni o […]

AKORI EKO: ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA Read More ยป