Yoruba

AKORI EKO: APOLA INU EDE YORUBA

Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Gbolohun le je eyo oro kan tabi akojopo oro ti oni itumo. Ihun gbolohun ede Yoruba dabi igba ti a bah un eni, a ni lati to awon oro wonyii jo lona ti yoo fi le e mu itumo ti o gbamuse lowo. A tun […]

AKORI EKO: APOLA INU EDE YORUBA Read More ยป