Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN

Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti jeyo. Bakan naa a le pe gbolohun ni oro ti a le pin si spola oro-oruko ati apola ise. ISORI GBOLOHUN EDE YORUBA Gbolohun eleyo […]

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN Read More »