Ede:- Akaye oloro geere

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012)

ASA:-  Atunyewo asa iranra-eni lowo

Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba ni lasiko.

Ipa Ti Asa Iranra-Eni Lowo N Ko Ninu Ise Ajumose At Oro Aje.

  1. O maa n je ki a le se ohun to po ni iwonba asiko
  2. Egbe alafowosowopo n so ni di nla ni pa se yiya owo sowo
  3. Ise ti a ba fi agbajo owo se maa n tete pari
  4. Iru fe ise bee si maa n yori si rere
  5. O n soni di aladaa-nla ati olowo repete

Asa Iranra-eni Lowo Ode Oni (Cooperative Society)

Egbe alafowosowopo je ona ti a n gbe ran ara eni lowo ni ode oni.  O je akojopo onisowo, agbe, ore,akowe, ise ijoba, aladugbo abbl.

Anfaani

  1. O je ona ti a n gba bo asiri omo egbe nipa sise eyawo
  2. O fi aye sile fun eyawo onilopo meji iye ti a ni
  3. Owo ti a ba fi pa mo sinu egbe yi kii din, lile ni o maa n le
  4. O n mu ki eniyan ni ajeseku tabi ohun ini bi ile, ero ifoso, ile, oko abbl.
  5. Dida owo pada omo egbe rorun purpa

Aleebu

  1. Omo egbe miiran le maa da owo ti o ya pada
  2. Awon alakoso egbe le se owo egbe kumokumo (Mis-management of funds).

Igbelewon:-

  1. Salaye asa iranra-eni lowo
  2. Ko ipa meta ti asa iranra-eni lwo n ko ninu ise ajumose ati oro aje
  • Salaye asa iranra-eni low ode-oni, anfaani, ati aleebu re se koko.

 

Ise Asetilewa :-  N je iranlowo pon dandan? Salaye egbe alafowosowopo lekun -un -rere gege bi ona iranra-eni-lowo ode oni ti ko se fowo ro seyin lawujo

 

LITERESO:-  Kka iwe Apile ko ti ijoba yan.

See also

Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru

Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)

OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)

OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)

AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE

Acadlly Playstore Brand logo 350 x 350