Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole
Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re
Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun
Salami :- Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o
Adunmi :- Bi o se emi ati ile mi, buburu kan ko ni subu lu wa o
Alake :- Adura re dara sugbon oni-mo taara eni nikan ni o ore mi —– (erin po)
Salako :- Ati awa ati ebi wa a ko ni fi wa rubo odun 2015 (Amin)
Alake :- Amin o —–
Salami :- Alake, jowo bi e ba ti n lo, e ki lo fun awako yii ki o maa sare aspajude o
Alake:- o seun salami, edumare yo so ipade wa o.
Aduni:- Ri daju pe o mu ebun odun wa fun omi ore re Pataki bi o ba ti de
Salako:- Odun a yabo fun gbogbo wa
Salami:- Amin
Alake:- E yin ore e ki le o
Igblewon:-
- Yabo ninu ayoka yin tumo si _________________
- Ta ni o n rin irin ajo ?
- Awon wo ni o n sare asapejude loju popo ?
Ise Asetilewa :-
- Ore meloo ni o wa ninu ayoka oke yii ? (a) mefa (b) meji (d) marin
- Ilu ________ ni alake n lo (a) ebonyi (b) Ibadan (d) idonre
- Ta ni onimo-taara-eni-nkan ? (a) salako (b) salami (d) adunni
- ___________ ko wo aago enikeni se ijoba re (a) Olodumare (b) oluko (d) aare Buhari
- Akole ti o ba ayoka yii mu ni ___________ (a) ore mi (b) ore asapejude (d) odun wole de
ASA:- Iwa Omoluabi
Omoluabi ni omo ti a bi ti a si ko ti o gba eko rere.
Ise ati iwa omoluabi bere lati inu ile ti a ti bii
OJUSE OMOLUABI NI AWUJO
- Iwa ikini
- Bibowo ati iteriba fun agba
- Ooto siso
- Iwa irele
- Iwa suuru
- Iwa igboran
- Iwa pele lawujo
- Fi fi ife han si omonikeji
PATAKI IWA OMOLUABI
- O maa n fi iru eni ti eniyan je han nitori eefin ni iwa
- O n buyi kun ni
- O n je ki eniyan tojo (pe laye)
- O maa n je ki a mo iru idile ti eniyan ti wa abbl.
Igbelewon :-
- Fun omoluabi loriki
- Ko ojuse omoluabi marun-un
- Salaye ise pataki iwa omoluabi lawujo
Ise Asetilewa : yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe ketalelogbon Eko kokandinlogun
LITERSO :- Kika Iwe Apileko ti Ijoba Yan.
See also
Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi
Ede:- Akaye oloro geere
Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru
Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)
OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)