Mr. Shodiya

Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa Igba lona ogun

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA Read More »

Yoruba

AARE BOOLU

Femi:         Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo:         Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi:         Mo rii. O dun mi wonu eegun. O dabi eni pe Refiri ti fon fere ki Kola to gba boolu naa

AARE BOOLU Read More »

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko –

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA Read More »

Yoruba

AKORI EKO: MOFIIMU

Mofiimu ni ege tabi fonran ti o kere julo ti o si ni ise ti o n se (tabi ihimo kikun) ninu ihunoro. Apeere eya moffimu ni oju, omo, owo, alaafia, eemi, egbon ati, ai, a, i, on. A ko le se atunge awon ege mofiimu oke wonyi mo ti a ba ge e, won

AKORI EKO: MOFIIMU Read More »

Yoruba

AKORI EKO: ORO – ISE

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro

AKORI EKO: ORO – ISE Read More »

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly