Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AMI OHUN

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

IRO KONSONANTI

Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, s, t, w, y. APEJUWE IRO KONSONANTI AKOONU Iro Konsonanti: ni iro […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

IRO FAWELI

Iro-Ede -; ni ege ti  o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

EYA ARA IFO

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.   EYA ARA IFO EYA ARA IFO […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

ORUNMILA

Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AWON ORISA ILE YORUBA

Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si.  Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun,  orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa ipin keji ni awon eniyan ti a so di orisa nitori ise  ribiribi owo won […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE

AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe.  A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo  +          kobo   =          kobokobo Odun  +          odun   =          odoodun Ale      +          ale       =          alaale Osu     +          osu      =          osoosu Osan   +          osan    =          osoosan Egbe   […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

ISEDA ORO-ORUKO

Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi  a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AYOKA ONISOROGBESI

Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo;               O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si  egbe wa. Baba Ramo     Haa! E seun o. Mo dupe o. Ayo                 Sugbon owo iwegbe re n ko- […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

ORI-ORO | SILEBU EDE YORUBA

AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Fun Apeere Wa-je oro onisilebu kan nitori pe ami ohun kan ni o wa lori re. I / we = 2 Ba / […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AROKO AJEMO ISIPAYA

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Ise ti mo fe lojo iwaju. Ki […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

Didaruko Faweli

A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a]        faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε]        faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese [i]         faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese [o]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) eyin roboto [ᴝ]       faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) eyin roboto [u]        faweli airanmupe […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

OSE KESAN-AN

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade pelu ariwo taki ki o se die ki iro jade ni irorun. Awon iro konsonanti […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO

“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku ni ebun oro-siso. Bi apeere, ti a ba so wi pe ‘Bawo ni nnkan’, awon eya ara kan wa ninu ara wa lati ori de […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si ki o to lo si Oke Itase. Idi niyi ti won fi n ki i ni ‘Okunrin kukuru Oke Igbeti’. Orunmila ni alakoso Ifa dida […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa Igba lona ogun […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

OSE KERIN-IN

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon ni: Oro ipinle; ati Oro ti a seda ORO IPINLE: Oro ipinle ni awon oro ti a ko le seda won. Apeere: Adie, eedu, omi, […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AARE BOOLU

Femi:         Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo:         Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi:         Mo rii. O dun mi wonu eegun. O dabi eni pe Refiri ti fon fere ki Kola to gba boolu naa […]

Acadlly

You cannot copy content of this page

error: Content is protected !!