Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO

“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku ni ebun oro-siso. Bi apeere, ti a ba so wi pe ‘Bawo ni nnkan’, awon eya ara kan wa ninu ara wa lati ori de […]

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO Read More »