Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

Didaruko Faweli

A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a]        faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε]        faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese [i]         faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese [o]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) eyin roboto [ᴝ]       faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) eyin roboto [u]        faweli airanmupe […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

OSE KESAN-AN

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade pelu ariwo taki ki o se die ki iro jade ni irorun. Awon iro konsonanti […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO

“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku ni ebun oro-siso. Bi apeere, ti a ba so wi pe ‘Bawo ni nnkan’, awon eya ara kan wa ninu ara wa lati ori de […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si ki o to lo si Oke Itase. Idi niyi ti won fi n ki i ni ‘Okunrin kukuru Oke Igbeti’. Orunmila ni alakoso Ifa dida […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa Igba lona ogun […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

OSE KERIN-IN

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon ni: Oro ipinle; ati Oro ti a seda ORO IPINLE: Oro ipinle ni awon oro ti a ko le seda won. Apeere: Adie, eedu, omi, […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AARE BOOLU

Femi:         Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo:         Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi:         Mo rii. O dun mi wonu eegun. O dabi eni pe Refiri ti fon fere ki Kola to gba boolu naa […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI

Aroko ti a ko to da lori itakuroso laaarin eniyan meji tabi ju bee lo ni a n pen i aroko oni-soro-n-gbesi. Abuda Aroko Onisoro-n-gbesi O maa n ni akopa bii ere ori itage Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Ise ni oogun ise                         Eni ise n se ko ma b’Osun                         Oran ko kan t’Osun                         I baa b’Orisa                         O di’jo to ba sise aje ko to jeun “Owuro lojo, ise la a fi i se ni Otuu’Fe”. Kaakiri ile Yoruba, ise ni won n fi owuro se. won gbagbo wi pe […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko – […]

Categories
SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term) Yoruba

AKORI EKO: AROKO AJEMO – ISIPAYA

Aroko ajomo-sispaya je aroko ti a fi n se isipaya awon ori oro to je mo ohun ayika eni. Aroko yii fi ara jo aroko asapejuwe sugbon o jinle ju u lo. Bi aroko asapejuwe se le fe ki o sapajuwe ‘Ile-iwe re’, aroko ajemo isipaya yoo fe ki a so nipa idagbasoke to de […]

Acadlly

You cannot copy content of this page

error: Content is protected !!