Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si ki o to lo si Oke Itase. Idi niyi ti won fi n ki i ni ‘Okunrin kukuru Oke Igbeti’. Orunmila ni alakoso Ifa dida […]

AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA Read More »