AKOLE ISE: LITIRESO APILEKO

Eyi ni litireso ti a se akosile ni gba ti imo mooko – mooka de si ile wa. Litireso apileko pin si ona meta, i Ewi ii Ere-Onitan iii Itan aroso Litireso Apileko – Itan aroso koko…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions

Eyi ni litireso ti a se akosile ni gba ti imo mooko – mooka de si ile wa. Litireso apileko pin si ona meta, i Ewi ii Ere-Onitan iii Itan aroso Litireso Apileko – Itan aroso koko…

Asa jeyo ninu Ede Yoruba ninu ipede bii owe, akanlo-ede, ewi ,ise sise abbl. Apeere OWE ASA TI O JEYO EKO TI AWON ASA YII KO WA 1 N o le waa ku ko le ri oye ile…

Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo 9 Eesan-an 10 Eewaa 11 Ookanla 10+1=11…

AWON LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN KAN TABI OMIIRAN NI ILE YORUBA NI WONYI, i Oya – pipe ii Esu – pipe iii Orin – arungba iv Ijala -sisun v Sango – pipe vi Iyere vii…

Akoto ni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia …

Litrreso alohun ni litireso ti a fi ohun enu gbe jade ti a jogun lati odo awon babanla wa. Apeere litireso alohun ajemayeye ni i Ekun Iyawo ii rara ii Bolojo iv Apepe v Dadakuada abbl Ekun iyawo…

Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi…

Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I …

i ba – ta(shoe) (dd) – kf – kf ii E – we(leaf) (rd) – f – kf iii A– ja(dog) (rm) – f – kf iv Ba – ba (father)(dm) – kf – kf v Ti – ti(a name…

Ami ohun ni o maa n fi iyato han laarin iro kan si iro keji. Ohun Isale \ (d) o doju ko opa osi Ohun aarin – (r) O wa ni ibu Ohun Oke / (m) O doju ko apa…

ALIFABEETI JE AKOJOPO LETA TI ASE AKOSILE RE GEGE BI IRO NINU EDE YORUBA. ALIFABETI EDE YORUBA Aa Bb Dd Ee Ee Ff Gg GB gb Hh Ii Jj Kk Ll Mm Nn Oo Oo Pp Rr Ss Ss Tt …
Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo Sipele Ode Oni Iddo Ido Otta Ota Jebba Jeba Offa Ofa Ebute-Metta Ebute-Meta Ottun Otun Shagamu Sagamu Oshogbo Osogbo Shaki Saki Shango Sango Ilesha Ilesa …

AKOLE ISE: Igbagbo Yoruba Nipa Orisirisi Oruko Ile Yoruba. Igbagbo Yoruba ni pe “ile la n wo ki a to so omo loruko”. A kii dede fun omo ni oruko ni ile Yoruba, akiyesi iru ipo ti omo naa wa…

Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati…

Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika apeere ibeere ti owa labe akaye i.ibeere ewo-ni-idahun iii.Ibeere agboroko EKA ISE: ASA AKOLE ISE OMO BIBI ( ORO…

Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta Figo 300 Oodunrun 305 Oodunrun ole-marun-un 310 Oodunrun ole-mewa 315 Okooleloodunrun odunarun-un 320 Okooleloodunrun 325 Okooleloodunrun ole-marun-un 330 Okooleloodunrun ole-mewaa 335 Ojileloodunrun odin marun-un 345 Ojileloodunrun ole-marun-un 350 Ojileloodunrin ole-mewaa 360 Otaleloodunrin 365…

Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA 101…

Litireso je ona ti Yoruba n gba lati fi ero inu won han lori ohun ti a je koko tabi iriri aye won. ISORI LITIRESO Litireso alohun ni litiresso ti a fi ohun enu gbe jade ti a jogun lati…

Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba. ISE IKOKO MIMO: ise ikoko mimo wopo ni agbegbe Ilorin, oyo, ipetunmodun, ise obinrin ni ise ikoko mimo, awon ohun elo ikoko mimo ni wonyi; Amo, omi, odo, isaasun obe, ekusu agbado.…

Igbelewon : Ise asetilewa: Gege bi esin re, salaye ilana igbeyawo ode-oni OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o. Gbolohun je akojopo oro ti o ni oro ise ati ise ti…