SS 3 Yoruba (1st Term)

Yoruba

AKORI EKO: MOFIIMU

Mofiimu ni ege tabi fonran ti o kere julo ti o si ni ise ti o n se (tabi ihimo kikun) ninu ihunoro. Apeere eya moffimu ni oju, omo, owo, alaafia, eemi, egbon ati, ai, a, i, on. A ko le se atunge awon ege mofiimu oke wonyi mo ti a ba ge e, won […]

AKORI EKO: MOFIIMU Read More »

Yoruba

AKORI EKO: ORO – ISE

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro

AKORI EKO: ORO – ISE Read More »

Acadlly
error: Content is protected !!