Yoruba

AKOLE ISE: KIKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN

AKOLE ISE:          Igbagbo Yoruba Nipa Orisirisi Oruko Ile Yoruba. Igbagbo Yoruba ni pe “ile la n wo ki a to so omo loruko”. A kii dede fun omo ni oruko ni ile Yoruba, akiyesi iru ipo ti omo naa wa nigba ti a bi, ipo ti ebi wa tabi ojo ati asiko ti a bi […]

AKOLE ISE: KIKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN Read More »