Yoruba

AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE

Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu mi abbl. Aroko lori Ile-Iwe mi Oruko Ile-eko mi ni […]

AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE Read More ยป