Litireso apileko ere-onitan ni iwe ere atinude ti onkowe ko lati so ohun ti o sele ninu itan tabi ti o sele loju aye. Apeere iwe ere-onitan ni “Efusetan Aniwura ti Akinwumi Isola ko Onkawe ere-onitan gbode mo awon koko wonyi, O gbodo mo nipa igbesi-aye onkowe O gbodo mo itan inu iwe naa […]
![AKOLE ISE: AWON LITIRESO APILEKO ERE-ONITAN 1 Yoruba](http://acadlly.b-cdn.net/wp-content/uploads/2022/07/Yoruba.jpg)