Yoruba

AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA

ALIFABEETI JE AKOJOPO LETA TI ASE AKOSILE RE GEGE BI IRO NINU EDE YORUBA. ALIFABETI EDE YORUBA Aa     Bb    Dd    Ee    Ee     Ff    Gg     GB gb   Hh    Ii    Jj    Kk    Ll    Mm    Nn    Oo    Oo      Pp      Rr      Ss      Ss      Tt    Uu     Ww       Yy Apapo alifabeti ede Yoruba je meedogun (25) Ona meji ni a le

AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA Read More »

AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Ise ni oogun ise                         Eni ise n se ko ma b’Osun                         Oran ko kan t’Osun                         I baa b’Orisa                         O di’jo to ba sise aje ko to jeun “Owuro lojo, ise la a fi i se ni Otuu’Fe”. Kaakiri ile Yoruba, ise ni won n fi owuro se. won gbagbo wi pe

AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI Read More »

Ede:- Akaye oloro geere

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:-  Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba ni lasiko. Ipa Ti Asa Iranra-Eni Lowo N Ko Ninu Ise Ajumose At

Ede:- Akaye oloro geere Read More »

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN

AWON LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN KAN TABI OMIIRAN NI ILE YORUBA NI WONYI, i               Oya – pipe ii              Esu – pipe iii             Orin – arungba iv             Ijala -sisun v              Sango – pipe vi             Iyere vii            Ese – Ifa   ESA – IFA / ORUNMILA: Awon olusi re ni babalowo

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN Read More »

AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko atonisona asotan Aroko oniroyin Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko Yiyan ori-oro: A

AKOLE ISE: AROKO KIKO Read More »

ASA ELEGBEJEGBE

ORIKI ORISII IPA TI WON N KO NI AWUJO AKOONU Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won. Ni aye atijo,iwonba ni ise ti ijoba maa n se fun awon ara ilu.igbega ati idagbasoke ilu tabi

ASA ELEGBEJEGBE Read More »

AKOLE ISE: LITIRESO APILEKO

AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57 58 Eeji din logota 60-2=58 59 Ookan din logota 60-1=59 60 Ogota

AKOLE ISE: LITIRESO APILEKO Read More »

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e

EKA ISE: EDE Read More »