Yoruba

AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN

Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION )   EKA ISE: ASA AKOLE ISE: ISINKU Isinku ni eye ikeyin ti a […]

AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Read More »