AKORI EKO: ATUNYEWO AAYAN OGBUFO

Aayan ogbufo ni itumo ede lati ede kan si omiran, paapaa julo ede geesi si ede Yoruba. Amuye for Ogbufo Gbigbo ede mejeeji: a gbodo gbo ede mejeeji daradara, eyi ni ede ti yoo tumo ati ede ti yoo tumo re si. Mimo ko ati mimo kaa: ogbufo gbodo le ka ede mejeeji daradara nitoripe […]

AKORI EKO: ATUNYEWO AAYAN OGBUFO Read More ยป