SS 3 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

Yoruba

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI

ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE) IGBESE IGBEYAWO                                 ALAYE Ifojusode                    Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin. Iwadii                         Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu. Won yoo tun se, iwadi lowo ifa. Alarina                       Alarina ni won yoo maa ran si ara won (oko ati Iyawo afesona), Boko ba moju […]

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI Read More »

Yoruba

ETO ISELU ODE-ONI

Ni aye ode-oni eto iselu ti yato patapata is ti aye atijo. Ni aye ode-oni, eto iselu ti aye ode-oni ni a n lo gomina ni Olori ati alase ni ilu kookan ti o si ni awon komisanna ti won jo n tuko eto ilu. Loooto ni awon oba si wa sugbon won ko ni

ETO ISELU ODE-ONI Read More »

Yoruba

ISEDA ORO-ORUKO

IHUN ORO (ISODORUKO) IGBESE Bi a se n seda oro oruko nipa lilo afomo ibere AKOONU:- Iseda oro-oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo.  Bi  a ba fe seda oro oruko eyi ni awon igbese ti a ni lati tele. Nipa lilo afomo ibere Nipa lilo afomo aarin Nipa sise

ISEDA ORO-ORUKO Read More »

Yoruba

ORO – AYALO

Inu ede ti a ti n ya oro lo. Ona ti a n gba ya oro wonu ede Yoruba.   Akoonu Oro – ayalo -: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede miiran Oro – ayalo -: ni mimu oro lati inu ede kan wo inu ede

ORO – AYALO Read More »

Yoruba

FONOLOJI EDE YORUBA

Foniimu konsonanti Foniimu faweli ati ohun Eda foniimu konsonanti ati faweli Akoonu (Iro aseyato) Foniimu ni awon iro ti o le fi iyato han laaarin oro kan tabi omiran Ap Foniimu ni /b/ /d/ /t/, eyi ti o tumo si pe  bi a ba fi iro kan dipo ikeji iyato yoo wa Ap Ede Ere

FONOLOJI EDE YORUBA Read More »

Yoruba

ASA ELEGBEJEGBE

ORIKI ORISII IPA TI WON N KO NI AWUJO AKOONU Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won. Ni aye atijo,iwonba ni ise ti ijoba maa n se fun awon ara ilu.igbega ati idagbasoke ilu tabi

ASA ELEGBEJEGBE Read More »

Yoruba

SILEBU EDE YORUBA

AKOONU Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere: Ajayi:              A-ja-yi  =         silebu meta Olabisi             O-la-bi-si         silebu merin. Adeleke           A-de-le-ke       silebu merin Olopaa             O-lo-pa-a         silebu merin Gbangbadekun  gba-n-gba-de-kun     silebu marun-un.   Odo Silebu: ni apa ti o se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Iro

SILEBU EDE YORUBA Read More »

Yoruba

AKORI EKO: MOFIIMU

Mofiimu ni ege tabi fonran ti o kere julo ti o si ni ise ti o n se (tabi ihimo kikun) ninu ihunoro. Apeere eya moffimu ni oju, omo, owo, alaafia, eemi, egbon ati, ai, a, i, on. A ko le se atunge awon ege mofiimu oke wonyi mo ti a ba ge e, won

AKORI EKO: MOFIIMU Read More »

Yoruba

AKORI EKO: ORO – ISE

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro

AKORI EKO: ORO – ISE Read More »

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly