Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba

Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya gbolohun ti o wa ninu ede yoruba Gbolohun abode Gbolohun…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Access comprehensive Yoruba Language notes for JSS 2 students, covering the 1st, 2nd, and 3rd terms.
These notes are designed to provide clear explanations of all key topics in the syllabus, making it easier for students to revise and prepare for exams.
Whether you’re in class or revising independently, these notes will help reinforce your understanding of Yoruba.
Download JSS 2 Yoruba Language notes for 1st, 2nd, and 3rd term, which covers key topics and syllabus areas. Perfect for exam preparation and revision.

Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya gbolohun ti o wa ninu ede yoruba Gbolohun abode Gbolohun…

Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :- Awon awako n sare asa pajude loju…

Akaye: Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yei yekeyeke. Orisi ayoka ninu akaye Akaye oloro geere Akaye ewi Akaye oni isoro-n-gbesi Igbese Ti A Ni Lati Tele Ki Ayoka Le…

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti…

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012 Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT) Ona ti a le gba dena ogun Ki ife ti o gbona wa laarin awon ara ilu Ki asoye…

Aroko atonisona asotan ni aroko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju wari tabi awon ise ti a gbo lenu enikan Ilana Fun Kiko Aroko Oniroyin Koko oro:- Eyi ni oro oro aroko Ero:- Akekoo gbodo…

AKOLE ISE:- Ede:- Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori oro Aroso Asotan Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo…

Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe

Aroso alapejuwe ni sise apejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to sele gege bi a se rii g an-an pelu ohun enu. Aroso ni ki si ni akosile ohun enu ni a fi n se apejuwe isele naa. Apeere ori oro…

Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye) Ose keji: Ede aroso alapejuwe Asa-asa iranra-ero lowo Litireso-ewi alohun to je mo…
Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo Sipele Ode Oni Iddo Ido Otta Ota Jebba Jeba Offa Ofa Ebute-Metta Ebute-Meta Ottun Otun Shagamu Sagamu Oshogbo Osogbo Shaki Saki Shango Sango Ilesha Ilesa …

AKOLE ISE: Igbagbo Yoruba Nipa Orisirisi Oruko Ile Yoruba. Igbagbo Yoruba ni pe “ile la n wo ki a to so omo loruko”. A kii dede fun omo ni oruko ni ile Yoruba, akiyesi iru ipo ti omo naa wa…

Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati…

Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise itupale ayoka ni finifinni fifi imo ede, laakaye ati iforabale…

Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta Figo 300 Oodunrun 305 Oodunrun ole-marun-un 310 Oodunrun ole-mewa 315 Okooleloodunrun odunarun-un 320 Okooleloodunrun 325 Okooleloodunrun ole-marun-un 330 Okooleloodunrun ole-mewaa 335 Ojileloodunrun odin marun-un 345 Ojileloodunrun ole-marun-un 350 Ojileloodunrin ole-mewaa 360 Otaleloodunrin 365 Otaleloodunrun…

Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA 101…

Litireso je ona ti Yoruba n gba lati fi ero inu won han lori ohun ti a je koko tabi iriri aye won. ISORI LITIRESO Litireso alohun Litireso apileko Litireso alohun ni litiresso ti a fi ohun enu gbe jade…

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA Eni hihun Ikoko mimu Irin riro Aro dida Igba finfin abbl. Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba. ISE IKOKO MIMO: ise ikoko mimo wopo ni agbegbe Ilorin, oyo, ipetunmodun, ise obinrin ni…

Igbelewon : Kin ni gbolohun onibo? Ko isori gbolohun onibo Salaye asa igbeyawo ode-oni lekun-un-rere Ise asetilewa: Gege bi esin re, salaye ilana igbeyawo ode-oni OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun…

Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle…