EYA GBOLOHUN
Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo… Read More »EYA GBOLOHUN
Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo… Read More »EYA GBOLOHUN
Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun… Read More »AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON
Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo… Read More »AKOLE ISE – SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA
Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA
Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni… Read More »AKORI EKO: ERE IDARAYA
Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN
JE OLOGBON OMO A ko mi nifee Mo mo fee su A ko mi lror Mo moro atata I pe Awon agba lo ko mi ni samusamu Ti mot i… Read More »AKORI EKO: EWI AKOMOLEDE
Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku. Ni ile Yoruba, ayeye isinku agba je ohun Pataki ti o fese mule ni awujo awon Yoruba paapaa ti o ba… Read More »ASA ISINKU NI ILE YORUBA
Fonoloji ni imo eto amulo iro lapapo. Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori… Read More »AKORI EKO: FONOLOJI EDE YORUBA
Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko… Read More »AKOLE ISE: AROKO KIKO
Akoto ni sipeli tuntun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati fi maa ko ede Yoruba sile. Awon ayipada ti o de ba… Read More »AKOLE ISE: AKOTO EDE YORUBA
Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon… Read More »AKOLE ISE: SILEBU
Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro. Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji; Iro ohun geere Iro ohun eleyoo… Read More »AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN)
Ouje ni awon ohun ti eniyan ati aranko n je tabi mu ti o fun ara wa ni okun ati agbara. Won ni “Bi ebi ba kuro ninu ise, ise… Read More »AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA
Apejuwe iro konsonanti Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi gbe won jade. A le pin iro konsonanti si ona wonyi; Ibi isenupe… Read More »AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE
Ere – onise – ese/iwi egungun , ijala Oriki itan isedele tabi eyi to n so idi abajo litireso atenudenu Yoruba ni eyi, awon ohun ti o n suyo nibe… Read More »EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN
AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA Apejuwe iro faweli A le sapejuwe iro faweli ni ona merin wonyi; Ipo ti afase wa Apa kan ara ahon to gbe… Read More »ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA
AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin… Read More »EKA ISE: EDE
A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a] faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e] faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε] faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju… Read More »Didaruko Faweli
AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le… Read More »OSE KESAN-AN