LITIRESO ALOHUN TO JE MO AYEYE

Litireso je ona ti Yoruba n gba lati fi ero inu won han lori ohun ti a je koko tabi iriri aye won. ISORI LITIRESO Litireso alohun Litireso apileko Litireso alohun ni litiresso ti a fi ohun enu gbe jade…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions

Litireso je ona ti Yoruba n gba lati fi ero inu won han lori ohun ti a je koko tabi iriri aye won. ISORI LITIRESO Litireso alohun Litireso apileko Litireso alohun ni litiresso ti a fi ohun enu gbe jade…

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA Eni hihun Ikoko mimu Irin riro Aro dida Igba finfin abbl. Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba. ISE IKOKO MIMO: ise ikoko mimo wopo ni agbegbe Ilorin, oyo, ipetunmodun, ise obinrin ni…

Igbelewon : Kin ni gbolohun onibo? Ko isori gbolohun onibo Salaye asa igbeyawo ode-oni lekun-un-rere Ise asetilewa: Gege bi esin re, salaye ilana igbeyawo ode-oni OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun…

Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle…

Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun alalaye Gbolohun Ibeere Gbolohun ase Gbolohun ebe Gbolohun ayisodi …

Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo Oro ayalo Apetunpe abbl. Atunyewo faweli ati konsonanti faweli…

Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni pe iye ibi ti ohun bat i jeyo ninu oro…

Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba…

Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti jeyo. Bakan naa a le pe gbolohun ni oro ti…

JE OLOGBON OMO A ko mi nifee Mo mo fee su A ko mi lror Mo moro atata I pe Awon agba lo ko mi ni samusamu Ti mot i menu ije Ife mi yato si teni ti n yinmu…

Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Gbolohun le je eyo oro kan tabi akojopo oro ti oni itumo. Ihun gbolohun ede Yoruba dabi igba ti a bah un eni, a ni lati to awon oro wonyii…

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku. Ni ile Yoruba, ayeye isinku agba je ohun Pataki ti o fese mule ni awujo awon Yoruba paapaa ti o ba je agbalagba ti o fi owo rori ku. Inawo ati…

Fonoloji ni imo eto amulo iro lapapo. Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori si gbolohun ede Yoruba ni a n pen i fonoloji.…

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko…

Akoto ni sipeli tuntun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati fi maa ko ede Yoruba sile. Awon ayipada ti o de ba kiko ede Yoruba sile ni wonyi SIPELI ATIJO SIPELI TUNTUN…

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa…

Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro. Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji; Iro ohun geere Iro ohun eleyoo Iro ohun geere: Eyi ni iro ohun ti o duro…

Ouje ni awon ohun ti eniyan ati aranko n je tabi mu ti o fun ara wa ni okun ati agbara. Won ni “Bi ebi ba kuro ninu ise, ise buse. Ouje ni oogun ebi. Ise Agbe ni ise ti…

Apejuwe iro konsonanti Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi gbe won jade. A le pin iro konsonanti si ona wonyi; Ibi isenupe Ona isenupe Ipo alafo tan-an-na Ibi isenupe: Eyi ni ogangan…

Ere – onise – ese/iwi egungun , ijala Oriki itan isedele tabi eyi to n so idi abajo litireso atenudenu Yoruba ni eyi, awon ohun ti o n suyo nibe ni oriki itan isedale ati awon asa ajogunba Yoruba. Kiki…